Zelda Williams
Ìrísí
Zelda Williams | |
---|---|
Williams in 2015 | |
Ọjọ́ìbí | Zelda Rae Williams 31 Oṣù Keje 1989 New York City, U.S. |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1994–present |
Parents |
|
Zelda Rae Williams (tí a bí ní Oṣù Keje Ọjọ́ ọ̀kàn-lé-lọ́gbọ̀n, ọdún 1989) [1] jẹ́ Òṣèré ará ìlú Amẹ́ríkà kan, Olùdarí, Olùgbéjáde, àti Òǹkọ̀wé. Ó jẹ́ ọmọbìnrin sí òṣèré àti apanilẹ́rìn-ín Robin Williams àti Olùgbéjáde fíìmù àti aláàánú Marsha Garces Williams. Gẹ́gẹ́ bí òṣèré ohùn, ó jẹ́ olókìkí jùlọ fún fífọ́ ohùn Kuvira nínú eré ọmọdé Nickelodeon, The Legend of Korra.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "So Jackson Heywood...". Zelda Williams verified Twitter page. July 21, 2014. Archived from the original on 2014-12-17. Retrieved September 2, 2014.
I turn 25 on the 31st.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Zelda Williams |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |