Tim Burton
Tim Burton | |
---|---|
Burton ní ọdún 2012 | |
Ọjọ́ìbí | Timothy Walter Burton 25 Oṣù Kẹjọ 1958 Burbank, California, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | California Institute of the Arts |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1971–present |
Notable work | Full list |
Olólùfẹ́ | Lena Gieseke , (m. 1987; div. 1991) Helena Bonham Carter (m. 2001; div. 2014) |
Alábàálòpọ̀ | Lisa Marie (1993–2001) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Website | timburton.com |
Signature | |
Timothy Walter Burton[lower-alpha 1] (tí a bí ní ọjọ́ Kàrùnlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1958) jẹ́ olùṣe fíìmù àti ayàwòrán ọmọ Amẹ́ríkà. Ọ̀pọ̀ mọ̀ọ́ fún pípinlesẹ̀ àṣà Goth ní ilé iṣẹ́ fíìmù Amẹ́ríkà. Ara àwọn eré tí ó ti gbé jáde ni Beetlejuice (1988), Edward Scissorhands (1990), The Nightmare Before Christmas (1993), Ed Wood (1994), Sleepy Hollow (1999), Corpse Bride (2005), Sweeney Todd: The Demon Barber of Fleet Street (2007), Dark Shadows (2012), Wednesday (2022). Burton tún dárí àwọn eré bi Batman (1989), Batman Returns (1992), Planet of the Apes (2001), Big Fish (2003), Charlie and the Chocolate Factory (2005), Alice in Wonderland (2010) àti Miss Peregrine's Home for Peculiar Children (2016).
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Museum of Modern Art (MoMA) web appearance for a 2009 exhibition on Tim Burton's art work.
- ↑ Magliozzi, Ronald S.; He, Jenny (2009) (in en). Tim Burton. The Museum of Modern Art. ISBN 9780870707605. https://books.google.com/books?id=9zWFrCfCyJ0C&q=%22timothy+walter+burton%22.
- ↑ "Biography". The Tim Burton Collective. December 15, 2003. Archived from the original on December 19, 2008.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found