[go: up one dir, main page]
More Web Proxy on the site http://driver.im/Jump to content

Ethel Barrymore

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ethel Barrymore
Barrymore in 1940
Ọjọ́ìbíEthel Mae Blythe
(1879-08-15)Oṣù Kẹjọ 15, 1879
Philadelphia, Pennsylvania, U.S.
AláìsíJune 18, 1959(1959-06-18) (ọmọ ọdún 79)
Los Angeles, California, U.S.
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1895–1957
Olólùfẹ́
Russell Griswold Colt
(m. 1909; div. 1923)
Àwọn ọmọ3
Parent(s)Maurice Barrymore
Georgiana Drew
ẸbíBarrymore family
Signature
Ethel with her brothers and their mother in 1890.

Ethel Barrymore je óṣèrè lóbinrin ilẹ america ti a bini óṣu August, 1879 to si ku ni óṣu june, ọdun 1959.Ethel Barrymore jẹ óṣèrè lóbinrin ti stage, screen pẹlú radio to si ṣisẹ fun ọdun mẹfa[1][2].

Igbesi Àyè Àrabinrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ethel ni a bi fun óṣèrè lọkunrin Maurice Barrymore ati óṣèrè lóbinrin Georgiana Drew[3].

Ethel fẹ̀ Russell Griswold Colt ni óṣu March ni ọdun 1882 ti wọn si bi ọmọ mẹta. Tọkọ Taya naa pinya ni ọdun 1923[4][5].

Óṣèrè lóbinrin ku lóri aisan ọkan si ilè rẹ ni Hollywood ni óṣu july ni ọdun 1959 ti wọn sin si óri iyẹ ti Calvary. Theatre ti Ethel Barrymore ni asọ lórukọ óṣèrè lóbinrin naa ni New York City[6][7][8].

Ethel dagba si ilú philadelphia nibi to ti lọ si ilè iwè ti Roman Catholic[9][10].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Barrymore gba irawọ kan lori Hollywood Walk of Fame lẹyin iku rẹ lori akitiyan rẹ ninu èrè oritage ni ọdun 1960[11]. Óṣèrè lóbinrin naa gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere to ranilọwọ Keji Didarajulo[12].