ookan
Yoruba
editEtymology
edit10 | ||||
[a], [b] ← 0 | 1 | 2 → | 10 → | |
---|---|---|---|---|
Cardinal: ọ̀kan, ení Counting: oókan Adjectival: kan, méní Ordinal: kìíní, kìn-ín-ní Adverbial: ẹ̀ẹ̀kan Distributive: ọ̀kọ̀ọ̀kan Collective: ọ̀kọ̀ọ̀kan |
Derived from owó (“cowrie”) + ọ̀kan (“one”).
Pronunciation
editNumeral
editoókan
- one (used when counting)
- Oókan, eéjì, ẹẹ́ta, ẹẹ́rin, aárùn-ún, ẹẹ́fà...
- One, two, three, four, five, six...
- Eélòó ni oókan àti oókan? — Oókan àti oókan jẹ́ eéjì.
- How much is one plus one? — One plus one equals two.
Noun
editoókan
- kobo or cent
- 2008 December 19, Yiwola Awoyale, Global Yoruba Lexical Database v. 1.0[1], number LDC2008L03, Philadelphia: Linguistic Data Consortium, , →ISBN:
- Ebi kò mọ̀ pé oókan kò sí lọ́wọ́, bí ojúmọ́ bá ti mọ́, ebi a máa pani
- Hunger does not know that one is in penury, each waking day, one is bound to be hungry
- center
- 2008 December 19, Yiwola Awoyale, quoting C. L. Adéoyè, Àṣà àti Ìṣe Yoruba[2], number LDC2008L03, 1979, Ibadan: Oxford University Press, page 324, quoted in Global Yoruba Lexical Database v. 1.0, Philadelphia: Linguistic Data Consortium, , →ISBN:
- Ṣẹ́ aṣọ funfun po dé oókan àyà òkú
- Fold over the white cloth to reach the center of the corpse's chest