[go: up one dir, main page]
More Web Proxy on the site http://driver.im/Jump to content

Nigerian Defence Academy

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nigerian Defence Academy
Established1964
TypeIle-Eko Ologun
Students1500
Undergraduatesyes
PostgraduatesMsc
Doctoral studentsPh.D
LocationKaduna, Nigeria
Website

Nigerian Defence Academy tabi Ile-eko Oro Abo Naijiria ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fun awon omo-ologun to wa ni ilu Kaduna[1][2]. Akoko ikẹẹkọ Ile-eko Oro Abo Naijiria jẹ ọdun marun (Ọdun mẹrin fun ti akadẹmi ati ọdun kan fun ti ologun)[3].

Ile-ẹkọ ọrọ abo Naigiria ni a dasilẹ ni óṣu February, ọdun 1964[4] gẹgẹbi atunṣè ti ilẹ british lati ṣè akoso ikẹẹkọ ti ólógun collẹgi RMFTC ti wọn pada sọ ni collẹgi ikẹẹkọ ologun ti ilẹ Naigiria ta mọsi NMTC ni ọjọ ti órilẹ ede naa gba óminira. Ilẹ ẹ̀kọ ologun kọ awọn óṣiṣè ti ologun, awọn ologun to mojuto omi ati awọn ologun to mojuto oke ofurufu[5][6].

Yara Ikawe ti Akadẹ̀mi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Yara Ikawe Ilẹ ẹkọ ọrọ abo jẹ ọkan gbogi fun ikọni ati ikẹẹkọ ti ologun. Yara Ikawe ti akadẹmi naa ni a da silẹ̀ ni ọdun 1963 lati gbe ikẹẹkọ larugẹ[7]. Oluṣakoso yara ikawe naa lọwọ ni Umar Lawal[8].

  1. Brigadier M.R. Varma (1964 – 1969) (Ọgagun akọkọ ti apapọ ilẹ India ti Ilẹ-ẹkọ abo)
  2. Alabojuto ologun David Ejoor (Óṣu January, Ọdun 1969 – Ọdun 1971) (Ọgagun akọkọ ti Ilẹ-ẹkọ abo ti ilẹ Naigiria)
  3. Alabojuto ologun Robert Adeyinka Adebayo (Ósu January, Ọdun 1971 – Óṣu March, Ọdun 1971)
  4. Alabojuto ologun Eyo Okon Ekpo (Óṣu March, Ọdun 1971 – Óṣu February, Ọdun 1975)
  5. Brigadier Illiya Bisalla (Óṣu February, Ọdun 1975 – Óṣu August, Ọdun 1975)
  6. Brigadier Gibson Jalo (Óṣu August, Ọdun 1975 – Óṣu January, Ọdun 1978)
  7. Brigadier E.S. Armah (Óṣu January, Ọdun 1978 – July 1978)
  8. Brigadier Joseph Garba (Ósu July 1978 – Óṣu July Ọdun 1979)
  9. Brigadier Zamani Lekwot (Ósu July 1979 – Ọdun 1982)
  10. Brigadier Abdullahi Shelleng (1982 – Ósu January Ọdun 1984)
  11. Alabojuto ologun Paul Tarfa (Ósu January 1984 – Ọdun 1985)
  12. Alabojuto ologun Peter Adomokai (Ọdun 1986 – Ọdun 1988)
  13. Alabojuto Ajagun Salihu Ibrahim (Ọdun 1988 – Ọdun 1990)
  14. Alabojuto Ajagun Garba Duba (Ọdun 1990 – Ósu February Ọdun 1992)
  15. Alabojuto Ajagun Aliyu Mohammed Gusau (Óṣu February 1992 – Óṣu January Ọdun 1993)
  16. Alabojuto Ajagun Mohammed Balarabe Haladu (Óṣu January Ọdun 1993 – Ọdun 1994)
  17. Alakoso Oṣiṣẹ Ile-Ọrun Al-Amin Daggash (Ọdun 1994 – Óṣu June Ọdun 1998)
  18. Alabojuto ologun Bashir Salihi Magashi (Óṣu June 1998 – 1999)
  19. Alabojuto ologun Thaddeus Ashei (2000 – 2002)
  20. Alabojuto ologun Okon Edet Okon (2002 – 2003)
  21. Alabojuto ologun Patrick Ademu Akpa (2003 – 2004)
  22. Alabojuto Ajagun Abel Akale (2004 – 2006)
  23. Alabojuto ologun Harris Dzarma (2006 – Óṣu August 2008)
  24. Alabojuto ologun Mamuda Yerima (Óṣu August 2008 – Óṣu August 2010)
  25. Alabojuto ologun Emeka Onwuamaegbu (Óṣu August 2010 – Óṣu December 2013)[7]
  26. Alabojuto ologun Muhammad Inuwa Idris (Óṣu December 2013 – Óṣu August 2015)
  27. Alabojuto ologun Mohammed Tasiu Ibrahim (Óṣu August 2015 – Óṣu October 2017)
  28. Alabojuto ologun Adeniyi Oyebade (Óṣu October 2017 – Óṣu November 2019)
  29. Alabojuto ologun Jamilu Sarham (Óṣu November 2019 – Óṣu March 2021)
  30. Alabojuto ologun Sagir Yaro (Óṣu March 2021 – Óṣu April 2021)
  31. Alabojuto ologun Ibrahim Manu Yusuf (Óṣu April 2021 titi di isin)[9][10]
  1. "Nigerian Defence Academy Kaduna – Free-Apply.com". Free-Apply.com. Archived from the original on 2023-06-11. Retrieved 2023-06-11. 
  2. "NDA completes field training of 342 cadets of direct short service course – The Sun Nigeria". The Sun Nigeria. 2022-11-19. Retrieved 2023-06-11. 
  3. Opejobi, Seun (2016-11-16). "NDA opens application for admission into 69th Regular Course". Daily Post Nigeria. Retrieved 2023-06-11. 
  4. "Nigerian Defence Academy". Crunchbase. 1964-02-05. Retrieved 2023-06-11. 
  5. Kumar, Dhruv (2022-10-11). "NDA Daily Routine: Training Schedule, Rules, and Regulations". BYJU'S Exam Prep. Archived from the original on 2023-06-11. Retrieved 2023-06-11. 
  6. Tauna, Amos (2017-08-06). "Boko Haram: NDA cadets complete three-week special training". Daily Post Nigeria. Retrieved 2023-06-11. 
  7. Umar, Lawal; Izah, Maimuna; Mohammed, Aisha Ibrahim (2018-07-28). "(PDF) Library Automation in the Nigerian Defence Academy: Issues and Challenges". ResearchGate. Retrieved 2023-06-11. 
  8. "Lawal UMAR - Academy Librarian - PhD IN LIBRARY AND INFORMATION SCIENCE - Nigerian Defence Academy, Kaduna - NDA". ResearchGate. Retrieved 2023-06-11. 
  9. "Nigerian Defence Academy NDA: List of Commandants till date". Opera News. 2020-07-20. Archived from the original on 2023-06-11. Retrieved 2023-06-11. 
  10. "Nigeria Defence Academy/Brief History/chronological list of NDA Commandants: From 1964 till date". YouTube. Retrieved 2023-06-11.